OGUN: AKANMOLE OBINRIN

ti oju obinrin koba gbe ona kan, ti o nfi gbogbo igba yale kakiri......
Ebami wa erupe ese osi obinrin na,
eye alapandede kan, 
eyo atare meje, 
apaadi todoju de ogiri, 
ao jo papo, 
ao da sinu efe owu tutu, 
ao di ni ikobere, 
ao kan mo enu ona abawole wa...... 
Odaju pupo, obinrin na a joko jee sinu ile ye ni, koda ki a lee jade funra wa, koni lo, orun ebe ni aparo nku si ni.

No comments

Powered by Blogger.