OGUN: QUICK MONEY (OWO KIAKIA)

Ti eniyan ba ni lo owo ni kiakia, ti ko si Ona abayo, ti irufe enibe ti gbiyanju sugbon ti ko yo, hmm, e je ka gbiyanju ise kekere yi. Ki Olorun fi ibukun si fun wa.

ISE NA NIYI 
* Ogede omini pipon kan
* Eye ombe gbigbe kan
* Odindi atare kan 
* Owu dudu ati funfun
* Schnapps Tabi Lord's 
* Peak Milk kan (olomi)

- A o fi obe la Ogede omini yen legbe 
- A o wa fi eye ombe yen sinu re
- A o fi Owu dudu ati funfun di papo daadaa
- A o gbe sinu ape ijonkan
- A o jo pelu odindi atare kan
- A o lo ninu ape yen kunna daadaa 
- A o wa fi peak milk lo gbogbo ebu yen leekanna ni deedee agogo kan oru (1a.m)
- A o da Otin Schnapps Tabi Lord's sinu cup ti a ba fi mu milk yen, a o fi shin eleyi to ba ku 
- A o gbe mu.

Fun iranlowo Tabi ibere 
Prophet Ona Ara, Erin Osun

No comments

Powered by Blogger.