Ogun: Lilo oyin igan (original honey)

BI ASE LE LO OYIN IGAN
Oyin Igan je okan lara ohun ti Olorun da fun
lilo wa sugbon opo wa ko mo bi ase le lo Idi
niyi ti ile ise toun lo ewe ati egbo fi so die lara
ona ti a le gba lo Oyin Igan.
1 OGUN OJU ; Ti Oju re ban se pin, tabi ti o
nyun o, ti o pon . Po Oyin ati alubosa funfun
pomon ara won. Maa kan si oju mejeji.
2. INU RIRUN; Lo Ewuro po mo Oyin ma lo sibi
meji lehin onje ale.
3. EGBO; Ewuro po mon Oyin ma fi si oju egbo
na.
4. EYIN OMODE; Oyin Igan ati Omi Osan wewe
mon ara won. Ki o si fun Omo na ni sibi kan
lemeji lojumo lehin onje.
5. IKO IFE (TUBERCULUS); Lo Atare, Ayu, Iyo
ati Orogbo pelu O yin Igan sinu Igo. Agba sibi
meji ni igba meta lojumo
6. AIRI ORUN SUN; Maa mu Oyin Igan sun.
Sibi meji lalale.
7. AILERA NINU OSU OBINRIN; Nkan osu to
nse segesege tabi to dudu (STOMACHPAIN)
Lo sibi Oyin Merinmerin ni Emerin lojumo.
8 ARONMOLEGUN; Lo Ewuro po mo oyin Igan
fi pa ibi ti on ro E. Ki o lo sibi meji li ojojumo
ni owuro kutukutu.
9AKANDUN TABI EEWO(BOIL). Lo Ewa ati
Kaun po mo Oyin Igan. Ma fira ibe.
10. OGBE INU(ULCER); Maa mu sibi Oyin meta
ni owuro kutukutu ni wakati kan ki o to jeun
aaro.
11. FUN ATO KIKI(SEMEN BOOST); Po eyin
tutu po mo Oyin sibi Maarun Lo gbogbo re
leekan naa.
12. IKO EGBE; Po Omi Igbin ati Oyin po mo ara
won .Sibi nla meta leemeta lojojumo. Omode
sibi kan laaro ati lale.
13. JEDIJEDI; Lo efirin, Omi Osanwewe po mo
Oyin Igan . sibi meta laro ati lale. Lojojumon.
14. ARUN ETI; Ti eti ban se oyun tabi ti o nrin
eniyan, fi omi gbigbona po iyo die ati oyin mo
ara won ma kan si eti mejeji laro ati lale.
15. KOKORO ENU; Po Oyin Igan po mo Osan
wewe fifo enu ni igba meta lojojumo.
16. ILE GBIGBONA; Lo ewuro po mo Oyin Igan
fi pa gbogbo ara sibi mejimeji, lemeta lojumo.
17. INU DIDUN LEHIN TO BINRIN BA BIMO;
Obinrin naa yio malo oyin sibi mejimeji lemeta
lojumo.
18. OMO TI O NTO SILE; Ki o maa mu sibi
Oyin Igan mejimeji sun titi tiko fi ni to sile mo.
19. IKO; Lo orogbo ki o daa sinu Oyin Igan
lehin nab ere si laa tabi ki o maa loo sibi kan
kan ni wakati metameta. Omode sibi kekere.
20. Maafi Oyin Igan mu Ogi tabi Tea. O dara.
21.OGUN OJUPIPON; Ma kan oyin si lemeta
loojumo.
22. ARUNSU; Lo ewe ejirin po mo oyin igan
sibi merin lemeta lojumo.
23 .ATOGBE; Omi ewe ewuro po mo Oyin Igan
sibi merin lemeta lojumo.
24. ROPAROSE; Fi ito re lo Oyin Igan lale.
25. EJE RIRUN; Lo ayu po mo Oyin Igan sibi
meta lojumo laro ati lale.
26. OKO LILE; Ma fi ogede dudu sise kan oyin
je.
27. OGUN EJE; Lo omunu ewuro po mo Oyin
Igan sibi meta loojo,.
28. INU RIRUN; Po iyo mo Oyin Igan sibi meta
lojumo.
29. FUN ARA DIDAN; Po Oyin Igan mo
adiagbon ma fi pa ara.
30. FUN IFA RUN AGBON.;Po etu mo oyin igan
ma fi pa.
31.FUN KOKORO; Lo eru awon ka imi ojo etu
po mo oyin igan mafi pa ara.
32. FUN ARAN; Omi osan wewe po mo oyin
igan sibi meta meta lojumo.
33.KI INU OBIRIN GBONA. Lo ayu po mo oyin
igan sibi merin lemeta lojumo.
34FUN IBA REFUNREFUN;Lo ayu po mo omi
osan wewe eyin ati oyin igan sibi merin ni igba
meta lojumo.
35. BI INA BA JO ENIYAN; Ma fi oyin pa ni
gbogbo igba.
36 BI OMI GBIGBONA BA DAJO ENIYAN. Ma fi
oyin igan pa.
37. ALEFO LARA OMODE; Lo eru awon ka etui
mi ojo po mo Oyin Igan ma fi pa ni gbogbo
igba (mase te fo rara).
38. OGUN EJE; Omi csan wewe eyin tutu mo
oyin igan sibi merin ni igba meta lojumo.
39. BI ARA BAUN GBONA:- Omi ewuro ti agbo
la ifi omi si ale fi iyo gbo a po mon Oyin Igan
sibi meji lee meta loju mo fi pa gbogbo ara.
40. BI INU BA DUN OBIRIN; Lo ayu po mo Oyin
Igan sibi meta lee meta lojumo .
41.OGUN ARUNSU; Fi iyo gbo efirin po mo
oyin igan sibi meta lee meta lojumo.
42.NKAN OSU OBIRIN TO UN SE SEGESEGE;
Lo ayu po mo omi osan wewe ati oyin igan
.sibi meta lee meta lojumo.
43. OGUN ATOSI. Omi jaganyin ;kun die, ayu
po mo Oyin Igan .sibi merin lee meta lojumo.
44.KI ENI TO BA NI ATOGBE ;Ma fi Oyin Igan
mu Ogi ati Tea. ma din sugar ku lara.
45.Ki eni to ba tile ni OGOJI ODUN Ma fi OYIN
IGAN mu Ogi tabi Tea.
46. OGUN DIDIN ISANRA KU; Ki o fi omi se
Haha agbado ki o ma fi Oyin Igan mu bi Tea
laro ati lale.
47. KI AGBALAGBA Ma lo Oyin Igan lati mu
Tea tabi Ogi O ma un je ki Opolo ji pepe......
OMIse tafi nta motor:- ipe oore were 2 a lo
Pelu afara oyin a fi fo motor na ose to baku a
le mo abe motor yen lo batan.O ODO AGBA

No comments

Powered by Blogger.