ogun: Miscellaneous Ogun
ISOYE
eiye ëga kan owo eyô meje ,ewe sikinrinmidin,o
didi atare kan ao jo po ao ma fi fôkômu
ADODUN
ewe ogbo ewe rekureku ewe sawerepepe ewe
amunimuye ao jo won po sinu oyin ao ma fira
oko ba obirin sun .ejo ema fi ise yi seka ooo
KI AMA JE OGUN NI OJU ORUN
Ewe ebure,ao finu oko wa leyin ti aba ba obirin
lopô ,ao jo pelu odidi atare kan ao fi sin gbere
yi orun wa ka odaju .iba ajunilo
ADA
eso werejeje 7 ,eyo atare 7 ao lô papo ao fi sin
gbere yipo apa mejeji .elo danwo
IFERAN ONI TIRO
ori aparo, iye agbe ,iye aluko ,odidi atare kan odi
jijo ao lo ebu na ,papo mon tiro ao male tiro na
fi seju si obirin
ajegun to daju
eso akoko,odidi atare kan ao jo po ao fi sin
gbere yi orun owo wa mejeji
okigbe (ada)
opolo aye kan ,ao ro isebe si lenu ,odidi atare
kan ao gbe opolo yen sinu ape leyin ti ati bu
isebe si ,ao mu atare na si legbe ao tun bu
isebe si ni gbogbo ara re ao jo po gbere yika
apa osi wa odaju
egba eleyi
isoye etu ibon ,oyin gidi ao ma bu etu yi si owo
ao ma la pelu oyin yi odaju
ogun iferan
ewe odundun ,iye adie abo,ao gun po ao da bintu
kan si ao tun po ao ma fipara walaï obirin yio
ma duwa ni
E je kia lo gbiyanju "AWURE ITAJA GIDI YI":
Ewe orijin tutu, ewe ogbo tutu ,ewe sawerepepe
tutu, Ako igbin nla kan,,, Sise re: Ao ko gbogbo
awon eroja yi sinu Odo, ao gun kunna ninu odo,
ao wa po mo ose dudu pelu oyin gidi ati lofinda
Danduala kan, wiwe laro kutu hai kia to lo si idi
ise aje wa..N.B: Akii fi omi po ose yi, oyin ati
lofinda ni omi re o,,,Eledumare Oba ni yio jeri
ara re lori ise yi kii se eniyan..
Thanks so much
ReplyDelete