Ogun to daju

AWURE OWO AGBOOJO
Ao fi iyerosun tefa ejiogbe si owo wa osi, a o pe ofo yi si: ajifolayin oruko ti anpe ifa, ojini kutukutu ke gbami gbami ni oruko ti anpe iwo esu odara, akirijaowo ni oruko ti anpe eyin iya mi osoronga, owo to wa lokun, to wa losa, ko lo ba mi ja wa loni lowo awon enia rere, tokunrin ati tobinrin - a o fe si oju ojo, a o fi eyitoku sa ori wa ni owuro kutukutu, ni owuro lan lo ogun yi, o daju
ASEJE ASINA
, ewe afara, ewe idi,ewe tanapowo,ewe owu akese, at a ijosi, epo iyo, kindinrin malu mejeji, ao gesi ona 8/8 iyere osun ao fi te eji ogbe, pelu gbolohun yi, gbolohun ::::::: olori ole ni lowo lowo, agbalagba ole ni tete LA, okanjua eniyan ni won ba ohun rere lowo re, IFA jeki won ba ohun rere lowo mi, ni owu akese bawo Oja owu okusu aparamo, igbe nlanla ni malu ke, owo nlanla ni kiwon ma wafun mi, idi loni kiwon di eru owo nlanla wa fun mi, afara loni kiwon fa ire owo nlanla wa fun mi, eji ogbe loni ki won GBE owo nlanla wa fun mi , adua, ao koje. Odaju
ATUDE OSE"
ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju
ITUWO ATUDE- aowa ewe ajeobale, epo igi ajeobale, egbo ajeobale, aolopo mose aopin ose na si ona meje, ti abafe we aowa ajadi apere kan aoko sinu re aowa we ose mejeje na lekan na telera won ninu apere yi kain kain meje ni aofi we ooo, AKIYESI, ti aba nwe lowo aogbodo soro, aosi gbodo siju le afi ti aba wekan tan ti atun fewe imin
ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje
EYONU AWON AGBA TODAJU
Ao wa Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo pupa lalale pelu adua odara pupo atude ni pelu odaju
EYONU ¤
Ewe Akoko ati Itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to sun... Ti o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi Akara elepo se sara fun enia meta pere odaju
EYONU ¤
Eru oju aro, epo obo ao lo kuna daadaa ao mo mo ose Lux ao maa fi we lalale.... Odaju
E YONU AWON IYAMI TURARI NI O ¤
Eku asin meta, Epo Obo, Epo Igi nla, Korowu ao gun papo, ao daa sinu try kan ao waa daa adin gidi si ao ro papo daadaa, ao saa si ategun, ao maa fin ni alale ki a to sun.... Awon Agba won yi maa yonu siwa
EYONU ASINA TIPATIPA ¤
Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun, ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni gbogbo igba..... Odaju
EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU
Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise
EYONU
Oga3,asin3,opolo3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe kileofimise,odindi atare 3,ao Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok
IMULE AGBA
Akara elepo16,eran menu,ao to akara yi round ninu ape ao fi eran sarin re ati odindi atare kan ao Jo po ama fi otin lo lalale
Eyonu ,ogede omini ati epo obo ati igbo mimu ao gun papo mo ose ,odaju
Etutu awon eleye kan reo:- alubosa funfun ao fi din eran namo tikoiti womi tiagesi ona merindinlogun, ao jo ako alangba kan pomo odidi atare kan ao lokuna ao da sori ipese na ao da epopupa lelori ao daniyan si ao gbelo sorita loru oganjo, odaju
OGUN ISOYE
Ori akuko adie togbo dada ao fi sinu agbada ijo nkan ao ko ewe akoko bomole ao fi odidi atare kan si ao jo ao lo kuna ao da oyin si ao ma fi ika arin ropo ao ma la isoye yi dara otun sise fun awon omo keke tiwan lo ile iwe ao so wipe ki wan ki ika arin bo kiwan la, inu roba ti owo (hand) lewo la dasi ti ao ti mala
OGUN TUDE TOODAJU. Egbo lapa funfun ti ori akitan,,,Egbo lapa pupa ti won fi se ogba School (ile iwe),Aso funfun opa kan,,opolo aye kan.ao ge egbo lapa funfun ati pupa si ona 16,kekeke.ao ko won si enu opolo yen,ao wa mu aso funfun yen ao di ni osuka ao gbe sinu Koko ijokan .ao gbe opolo yen si pelu atare kan,ao jo po ao fi ose ko,ao ma fi we
ATUDE AWON AGBA ..Egbo lapalapa eyikeyii.. Ao ge kekeke si inu ike kan.. Ao wa Alangba eyokan ao jo papo pelu odidi Atare kan ao lokuna dada .Ao wa da sinu egbo take kekeke yen........ Ao wa da HOT Sinab tabi Omin lasan sii.

No comments

Powered by Blogger.